Àkọ́wá
From Wikipedia
Àkọ́wá (proton) je owon abeatomu pelu agbára iná alapaotun pelu opo to je ona 1836 ju opo atanná lo. Akowa ati alaigbara ni a mo si abikun, to je pe ona ti a fi tipatipa de won mo inu inuikun atomu ni a mo si ipa atomu (atomic force).