From Wikipedia
Oju Ewe Imo Isiro
Ìmọ̀ Ìsirò jẹ́ èyí t'on jẹ mo nipa ọ̀pọ̀iye (quantity), nipa òpó (structure), nipa iyipada (change) ati nipa ààyè (space). Idagbasoke imo Isiro wa nipa lilo àfòyemọ̀ọ́ (abstraction) ati Ọgbọ́n ìrọ̀nú, pelu onka, isesiro, wíwọ̀n ati nipa fi fi eto s'agbeyewo bi awon ohun se ri (shapes) ati bi won se n gbera (motion). Eyi ni awon Onimo Isiro n gbeyewo, ero won ni lati wa aba tuntun, ki won o si fi ootọ́ re mulẹ̀ pelu itumo yekeyeke.
A n lo Imo Isiro ka kiri agbaye ni opolopo ona ninu Imo Sayensi, Imo Ise Ero, Imo Iwosan, ati Imo Oro Okowo. Bi a se n lo imo Isiro bo si apa eyi ti a n pe ni Imo Isiro Oníwúlò (Applied Mathematics). Apa keji Imo Isiro ni a mo si Imo Isiro Ogidi. Eyi je mo eko imo isiro to ko ti ni ilo kankan bo tileje pe o se se ki a wa ilo fun ni eyinwa ola.
Awon Orisirisi Nomba ti o wa
Awon Eka Imo Isiro
Eko Isiro |
Ipilese Imo Isiro |
Ero Nomba |
Imo Isiro Onijinle |
- Awon Onimo Isiro
- Itan Imo Isiro
- Imo Oye L'ori Isiro
- Sise Ami Isiro
- Ewa Imo Isiro
- Eko Imo Isiro
- Area of mathematics
|
- Ipilese Imo Isiro
- Ero Ikojopo
- Naive set theory
- Axiomatic set theory
- Mathematical logic
- Ero nipa Ise afihan
- Ero Ise Afiwe
- Category theory
- Awon agbagbo aipeyekun Gödel
|
- Ero Nomba
- Èrò Nọ́mbà fún Áljẹ́brà
- Ero Nomba fun Agbeyewo
- Isesiiro
- Awon Nomba
- Ipilese Agbagbo Isesiro
|
- Imo Isiro Onijinle
- Combinatorics
- Ero Iwon Ila
- Ero Ibanisere
- Iwon Itobiile Onijinle
- Ero Imo Sayensi Ero Olonka
- Ero L'ori Onka
- Complexity theory
- Ero Ise Ikede
|
Agbeyewo Ninu Imo Isiro |
Aljebra |
Iwon Itobile ati Imo Eya Ile |
Imo Isiro Oniwulo |
- Analysis
- Isiro Kalkulosi
- Isiro Kakulosi Igbegbooro
- Idogba Iseyato
- Isiro Kalkukosi Oniyekiye
- Isiro Agbeyewo Gidi
- Complex analysis
- Agbeyewo Alabase
- Agbeyewo Onibamu
- Ero L'ori Iwon
- Awon Alabase Otoo
- Isiro Iseiwon Onigun
- Ipilese Agbagbo Isiro Kalkulosi
|
- Aljebra
- Aljebra Akokose
- Aljebra Afoyemo
- Ero Group theory
- Ero Oruka
- Field theory
- Aljebra Onidipo
- Aljebra Atelera
- Aljebra Atelera Olopolop
- Aljebra Agbala Aye
- Ero Eto (Order theory)
- Ipilese Agbagbo Aljebra
|
- Iwon Itobisi Ile
- Topology
- General topology
- Algebraic topology
- Geometric topology
- Itobi Ile Efklidi
- Itobi Ile ti kise ti Efklidi
- Affine geometry
- Projective geometry
- Differential geometry
- Riemannian geometry
- Lie groups
- Algebraic geometry
- Four color theorem
- Pythagorean theorem
|
- Isiro Oniwulo
- Agbeyewo Nomba
- Mathematical biology
- Optimization
- Dynamical systems
- Financial mathematics
- Cryptography
- Mathematical physics
- Probability
- Statistics
- Operations research
|