Australia
From Wikipedia
Osirelia
Australia
Nínú ètò ìkànìyàn 1995, àwon ènìyàn tí ó wà ní orílè-èdè Australia lé díè ní mílíònù mókàndínlógún (19,089,000). Èdè Gèésì ni èdè tí wón fi ń se ìjoba ibè. Àwon tí ó ń so ó tó ìdá márùn dínlógórùn-ún nínú ogórùn-ún. Àwon tí èdè Gèésì jé èdè àkókó fún tó ìdá méjìlélógórin nínú ogórùn-ún gégé bí ó se hàn nínú ètò ìkànìyàn 1991. Àwon èdè, tí àwon tí ó ń se àtìpó ń so tó ogórùn-ún. Lára won ni Italian, Chenese, Arabic, Greek, Vietramese. Wón sì tún ń pò sí i ní pàtàkì àwon ènìyàn tí ó ń wo ilè náà láti ìlà-oòrùn Asai. Àwon tí ó ń so èdè Aborigine kò tó ìdá kan nínú ogórùn-ún