Economic saboteur
From Wikipedia
ECONOMIC SABOTEUR
Lílé: Wón ti kó gbogbo kàlòkàlò
Tó kówó wa lo ní Nàìjíríà
Òpòlópò ń sèwòn torí owó Nàìjirìà o mo wí
Ègbè: Ùbéfù ò nákó nana yeyè 445
Sùbùnàdò o nákó nana yeee
Lílé: Won ti kó gbogbo kàlòkàlò
Tó ń kó wa lówó ní Náíjíríà
Òpòlopò ń sèwòn torí owó Nàìjírìà o mo wí o
Ègbè: Ùbéfù ò nákó nana yeyè 450
Sùbùnàdò o nákó nana yeee
Lílé: Opo òsísé wón ra moto sona repete
Opo òmòwé wón pera won ni ‘Director’
Opélopé oba Edumare lo ń tójú wa ni Nàìjíríà o
Ìyàn iba ti pànìyàn torí owo wa tón kó lo o bàbá 455
Ègbè: Ùbéfù ò nákó nana yeyè
Sùbùnàdò o nákó nana yeee
Lílé: ‘Economic saboteur’ won ti kó gbogbo owó wa lo
Opé Bámèyí lóbá wa rówó wa gbà ò baba
Ègbè: Ùbéfù ò nákó nana yeyè 460
Sùbùnàdò o nákó nana yeee
Lílé: A rí lára ‘officer’ tó kó wa lówó je
A rí lára ‘Bank Manager’
To ti ko gbogbo owó wa sowò tàn
Ègbè: Ùbéfù ò nákó nana yeyè 465
Sùbùnàdò o nákó nana yeee
Lílé: Ùbéfù ò nákó nana yeyè
Sùbùnàdò o nákó nana yeee
Ègbè: Ùbéfù ò nákó nana yeyè
Gbogbo kàlòkàlò won ti kó gbogbo owó wa lo 470
Ègbè: Ùbéfù ò nákó nana yeyè
Sùbùnàdò o nákó nana yeee
Lílé: Ùbéfù ò nákó nana yeyè
Gbogbo òsìkà ènìyàn wón ti kowo
wa lo ni Nàìjíríà o mo wí 475
Ègbè: Ùbéfù ò nákó nana yeyè
Sùbùnàdò o nákó nana yeee
Lílé: Ùbéfù ò nákó nana yeyè
Gbogbo kàlòkàlò won tí
Kówó wa lo o baba 480
Ègbè: Ùbéfù ò nákó nana yeyè
Sùbùnàdò o nákó nana yeee
Lílé: Opélopé Bámèyí ló gba gbogbo wa sé
Àwon òsìkà ènìyàn ti kówó wa lo
Ní Naijiria mo so 485
Ègbè: Ùbéfù ò nákó nana yeyè
Sùbùnàdò o nákó nana yeee