Eko Aigbagbo Pe Olorun Wa (Atheism)
From Wikipedia
Eko Aigbagbo Pe Olorun Wa
Asawale, Paul
ASAWALE PAUL
ATHEISM: ÈKÓ ÀÌGBÀNGBÓ PÉ OLÓRUN WÀ.
Àwon Gírúkì (Greeks) ni wón kókó lo òrò yìí- Atheism. Tí abá fo sí wéwé ni wíwò mofólójì rè A + theos = Atheos. “A”- túmò sí “not” ni
ède Gèésì, èyí tí a le túmò sí “kò jé” ní èdè Yorùbá, “theos-túmò sí-“god”ní èdè Gèésì, èyí tí á jé “Olorun” ní ède Yorùbá. Tí a bá wá kan án pò á wá jé “atheos” ní Gíríkì, “not god” ní Gèésì, àti “ko je olórun ni ède Yorùbá.
KÍ NI ÀWON ELÉRÒ YÌÍ Ń SO
Àwon elérò yìí kò gbàgbó nínú wíwà olórun (Existence of God or gods) kankan bóyá ni mú aféfé ohun èlò ken, tàbí nínú èmí. Ní tiwon kò sí Olórun. Àwon elérò yìí ní àwon ní ìmò tàbí èye pé kò sí olórun hàn kò gbà pé Olórun wà. Won ní ìgbàgbó nínú olórun jé ìgba ohun asan gbo.
VOLTAIRE onímo ìjìnlè kan ni ó se agbáterù oye yìí.
ÀWON IYÀN WON:
(1) Wón ko gbogbo ònà ìkàsìn tàbí ònà àtijó ti àwon ènìyàn ti lò láti fi ìdí wíwà Olórun múle. Ara àwon ònà yìí ni a le ri nínú Bíbélì àti kùránì. Àwon mìíràn tilè gbàgbó wí pé Olórun wà nítorí àwon nnkàn tí o ń selè tàbí wà ní àyíká wa tí a kò lè mo yalè won. Wón ní Olórun nìkan ni ìtumò àwon nnkan wòn yìí. Àwon “Atheist” ni iró ni. Èyí kò fi hàn pé Olórun wà.
(2) Ìbèrù ìgbèyìn ayé tí a kò mo ni ó ń bami lérù tí a fi ń gbàgbó lórí ifa omírà jagun lórí àìsàn, ikú, òsì àti beebe lo. Èrò àbámò àti àìní ènòjinlè ni eléyìí.
(3) Gbogbo àwon àbùdá ti a fun àwon ti a pè ní Olorun yìí, a rà wón bo wón lórún nì.
(4) Ò soro láti gbè pe Olórun tí o ní gbogbo agbára tí ó sì mo ohun gbogbo lè jé ki ibi dé bá èdá owó o rè
(5) Láti so pè àdìtú ni àwon nnkan wònyìí fí èrò nípa Olórun hàn gégé bí ohun ti kò sí nínú ayé èdá kò si yé kí á kobiara sí i.
(6) Àwon elérò yìí tàbùkù ìgbògbó Olorun nínú Bíbélì àti kùránì. Wón tako olorun owú àti esan wón.
ÌPÌLÈ ÈRÒ ÈKÓ ÀÌGBÀGBÓ PÉ OLÓRUN WÀ
Ní àpá ìlà oòrùn àgbáyé ni èrò yìí ti kókó Gbile ní pàtó láti orílè èdè “India”. Èrò yìí je jáde láti inú òpòpolò èrò bíi “cationalism, Materialism” “Buddisim àti béèbéè lo. Ogbéni kan ti o se agbáterù rè jù ni ADVAITA VEDANTA ti ilú SHANKARA. Títi di bíi séńtury méjìdìnlógún (18th C.) kò sí eni tí ó gbódò so nípa èrò yìí nínú àwùjo àwon onígbàgbó. Wón gbàgbó pé èrò yìí lè kó bá ìwà omolùà bi ènìyàn àti ìwà ìbán-enígbépò sùgbón àwon elérò mìíràn tí a pè ní DEISM ní ìbámu pèlú onimò ìjìnlè kan –EPICURUS (341-270bc), tún so pé bí àwon Olórun bá tilè alà won kò ní nnkan-kan se pèlú ènìyàn tàbí wíwá rè. Òfun ìle Améríkà, èyí ti THOMAS JEFFERSON so pé o pa ààlà láàrin ìjo (church) àti ìlú ti esè rè mùlè pé kókó jabele ni òrò èsùn, kò gbódò kan ìlú. Bèrè lati (19th Century) Sentury mókàndínlógún àwon èlèrò yìí ti pò sí bíi:- Perry Bysshe, Tayler Coleridge àti béè béè lo. Wón so pé àtiowódá tàbí àfògbón-hun ní òrò èsùn. Wón ni ò kàn ń gba díè lára ohun rere àti díè lara ohun burúkú owó èdá ni.