Fitila wa
From Wikipedia
FÌTÍLÀ WA
Lílé: Fítííláà waa
Ègbè: Má fi wá sáyè yí lo
Lílé: Fíítíí Fitifi
Fíítíílaa waa 385
Ègbè: Ma fi wá sáyè yìí lo
Lílé: Ojú loba ara
Ègbè: Má fi wá sáyè yi lo
Lílé: Etí tí a fi ń gbó
Ègbè: Má fi wá sáyè yi lo 390
Ègbè: Enu táa fi ń korin
Ègbè: Má fi wá sáyè yi lo
Lílé: Esè ta fi ń rìn kiri
Ègbè: Má fi wá sáyé yí lo
Lílé: Ìyà tó jafójú 395
Ègbè: Jìnnìjìnnì baba è
Lílé: Ìyà tó jafójú
Ègbè: Jìnnìjìnnì iya e
Lílé: O pé mú sapá sáko jì eléyá e yò
Owó ti yóò pa wá o 400
Ègbè: Yàràbì má fi fún wa
Lílé: Isé ti yóò pa wá o
Ègbè: Yàràbì má fi fún wa
Lílé: Omo ti yóò pa wá o
Ègbè: Yàràbì má fi fún wa 405
Lílé: Omo ti yóò pa wá o
Ègbè: Yàràbì má fi fún wa
Lílé: Ìyàwó ti yoo pa wá o
Ègbè: Yàràbì má fi fún wa
Lílé: Ò saa kàwa báko jìn 410
Lílé: Olúségun Adétìméhìn mi oko joké
Adetimehin mi, oko joké
Ìwo ni bàbáa Sadé, bàbá Adéronké mi
‘Indian Connection’ mi
Omo won lòpólùyí ò jefòn 415
Ó ń fawo erin ín sodún
Ìyà tó jafójú
Ègbè: Jìnnìjìnnì baba e
Lílé: Ìyà tó jafójú
Ègbè: Jìnnìjìnnì iyá e 420
O pé mú sapá lo sáko jìn eléyá e yò
Lílé: Ówó ti yó pa wá o
Ègbè: Yàràbì má fi fún wa
Lílé: Omo ti yó pa wá o
Ègbè: Yàràbì má fi fún wa 425
Lílé: Aya ti yóó pa wá o
Ègbè: Yàràbì má fi fún wa
Lílé: Ìsé ti yóó pa wá o
Ègbè: Yàràbí má fi fún wa
Sawábáwà sáko jìn 430
Lílé: Òré o kú àtijó
Ègbè: Ó tójó métaa a dúpé lòní o
A tún pàde ò
Lílé: A lo wéré, a bò
Ègbè: A lo wéré, a bò 435
Lílé: A lo wéré, a bò
Ègbè: A lo wéré, a bò
Lílé: È bá so fún baálè pò pèèsì je ò
È bá so fún baálè pó pèèsì je o
Orlando tó ka wón láyà tààjò dé o 440 O yé teeeee