Gbana
From Wikipedia
GBANA (HEROINE)
Lílé: Ebe mó bè ò, eyin eyàn-an wa
E máse gbérohine tàbí cocaine
Wa síle mi ráárá 490
Ègbè: Wón ní mo sá gbáná
Wón ni mo sá gbáná
Wón fé rán mi léwon osù méfà nítorí igbááná
Lílé: Gbáná ò daa
Gbáná kìí sehun rere 495
Mo bè yín omo Nàìjríà
E má mu gbáná mó
Ègbè: Wón ní mo sá gbáná
Wón ni mo sá gbáná
Wón fé rán mi léwon osù méfà nítorí igbááná 500
Lílé: Orí ló yo mí lójó tón mú mi fún gbáná
Ojú orun ni mo wà
Mo ń bá ‘siesta’ mi lo
Ojú orina ni mo wà
Tí mo ń bá siesta mi lo 505
Ìgbájú no fi jí mi lójú orun o
Nítori gbáná gbáná gbáná
Ègbè: Wón ní mo sá gbáná
Wón ni mo sá gbáná
Wón fé rán mi léwon 510
Osù méfà nítorí igbááná
Lílé: Bámèyí kìí gbèbè tó ba ti mú won sígbáná
Ńse ló fèwòn sí won lésè nitori igbó
Ègbè: Wón ní mo sá gbáná
Wón ni mo sá gbáná 515
Wón fé rán mi léwon
Osù méfà nítorí igbááná
Lílé: Eni ba wojú tí mo ní a mo pékan ti dùn mí rí
Òkan soso tó kù
Wón tùn fé bá mi jirin 520
E gbà mí o.
Ègbè: Wón ní mo sá gbáná
Wón ni mo sá gbáná
Wón fé rán mi léwon osù méfà nítorí igbááná
Lílé: Má mu cocaine, má mu gbááná 525
Eni bá mu cocaine ìjoba Bámèyí
Á fojú è rí màbo tó bá fihan fáráyé
Ègbè: Wón ní mo sá gbáná
Wón ni mo sá gbáná
Wón fé rán mi léwon osù méfà nítorí igbááná 530
Lílé: ‘Family Planning’ won ni ke ma lo ‘condom’
Àìsàn burúkú ti tún wòlú tón pè ní ‘AIDs’
E ma lo ‘condom’, e ma ra ‘condom’
Torí ke mama kúkú òjijì o
E ma lo coo-n-dom 535
Ègbè: E ma lo condom, e ma ki condom
Tori ke mama kúkú òjijì
E ma lo Condom
Olómolórí ti won ní kó fètò sómobíbí
Torí ke mama séyún òjìjì o 540
E ma lo con-condom
Ègbè: E ma lo condom, e ma lo condom
Torí ke mama kúkú òjijì o
E ma lo condom
Lílé: E ma lo condom, e ma lo condom 545
Torí ke mama kúkú òjijì o
E ma lo co-condom
Ègbè: E ma lo condom,
E ma lo condom
Torí ke mama kúkú òjijì o 550
E ma lo condom
Lílé: E ma lo condom
E ma lo condom
Torí ke mama kúkú òjijì o
E ma lo condom 555
Ègbè: E ma lo condom,
E ma lo condom
Torí ke mama kúkú òjijì o
E ma lo condom
Lílé: Èbè mo be o, èyin èyàn wa 560
Ke má se gberoine tàbí cocaine
Yà sílé mi mó rara
Ègbè: Wón ní mo sá gbáná
Wón ní mo sá gbáná
Wón fé rán mi léwon osù méfà 565
Nítorí igbááná
Lílé: E ma lo condom,
E ma lo condom
Torí ke mama kuku òjìjì o
E ma lo coo-n-dom 570
Ègbè: E ma lo condom,
E ma lo condom
Torí ke mámà kúkú òjijì o
E ma lo condom
Lílé: E ma lo condom, 575
e ma lo condom
Torí ke mama kúkú òjijì o
E ma lo condom
Ègbè: E ma lo condom
e ma lo condom 580
Torí ke mámà kúkú òjijì o
E ma lo condom