Haladu Farin Tsoho
From Wikipedia
Ta’aziyar Haladu Farin Tsoho (Orin Idaro fun Oloogbe Haladu Farin Tsoho))
Contents |
[edit] Orin Ìdàrò fún Olóògbé Haladu Farin Tsoho
Ọlorun mo gbadura nitori ojise re
Forijin Haladu
Omo Barau, alagbara okunrin
Ki Ọlorun forijin Haladu
Ki o sun-un re 05
Ki Olórun foríjin Haladu
Kí Olórun dáàbòbó ibojì re
Nígbà ti Haladu wà láyé
Ó ní ìwà rere
Obi rè jé elerii 10
Àwon òré rè jé elérìí
Gbogbo ènìyàn je elérìí
Pé ó gbèrò rere, ó sì se rere
Haldu ni suuru àti ìteríba
Ó ní ìwà rere 15
Kì í fojú tenbelu enikeni
Kì í se àfojúdi sí eníkeni
Olórun, mo bè ó
Nítorí òjísé re
Kí ó dáàbòbo ibojì rè 20
Mò ń pe gbogbo alábàárò
Mo ń pe gbogbo òré
Mò ń pe àwon ará ilé rè
Nítorí Olórun
Enikéni tó bá fé gbàdúrà 25
Kí ó rántí Haladu
Olórun mo bè ó
Nítorí òjísé re
Ran awa tí ó kù sáyé lówó
Nítorí Halladu 30
Ìtàn ti fi hàn
Irinajo òjísé ńlá
Nígbà tí ó kúrò ní Mecca
Lo sí Mèdínà
Àwon ará Medina gbà á 35
Irú àwon tí ó gbà á
Ni Halladu jé
Gbogbo mùtúmùwà
Ti Olórun bá bù kún yin
Tí e ni orò 40
Ki e si mo ètò ènìyàn
Bi i ti Haladu Farin Tsoho
Àwon òkú ń sinmi
Ki Olórun dáàbòbo ibojì wa
Kí Olórun dáàbòbo ibojì mi 45
Bí a bá wa lónìí
Òla, a kò sí mó
A gbódò máa ranti pé
A gbódò fi ayé sílè fun àwon omo wa
Àwon náà gbódò fi sílè fómo 50
Nítorí ìtàn fi han pe
Dandan ni ikú fun èyí
Dandan ni fún iyen
Dandan ni fún èyí
Aso ni ikú 55
Tí ó bá se é se
N bá ti bo aso ikú tèmi sonù
N bá ti bùn elòmìíràn
Sùgbón, ala ti ko le se ni èyí
Ọgbeni, nigba ti o ba file bora bí aso 60
Bi o ba jé arékérekè nílé ayé
Àrékérekè ni yo tè lé o
Tí o bá jé òfófó láyé
Òfófó ni yóò tè lé o
Bí o bá jé ońijìbìtì láyé 65
Jìbìtì ni yóò tè lé o
Tí o bá jé aláìsègbè láyé
Àìsègbè ni yóò tè lé o
Bí isé owo re bá gún láyé
Ònà re yóò gún lorun 70
Bí o bá se rere nílé ayé
Rere ni yóò tèlé o
Lójó yen kò sí pé ènìyàn pàtàkì ni mi
Àfi iwa àti ìsìn re
Àfi ohun tí o gbáyé se 75
Olórun wo àwon ènìyàn
Olórun wo àwon ènìyàn re
Dábòbo ibojì wa
Bí i télè
Dáàbòbò ibojì mi 80
Ìtàn ti fi hàn
Iwa buruku jòwò maa ló
Ó sàbá máa ń tè lé àwon ènìyàn
Àwon ènìyàn ń sá lo
Wón sí fílà lórí 85
Wón ni àwon ti sá àsálà
Nísinsinyìí, òtító ni
Nnkan èèwò ń sáré
Àwon ènìyàn náà ń sáré
Tè lè e lèyìn 90
Wón ni àwon ti lé e bá
Olórun wo àwon ènìyàn re
Ìbùkún òjísé Olórun
Dáàbòbò ibòjì wa
Olórun, dáàbòbò ibòjì mi 95
Nítorí tí a bá bí omo
A ó mú un lo sí il ilé ìwé
Olúkó yóò máa ko o lójoojúmó
Bí a se ń gé èékánná
Bí a se n fo èwù sòkòtò àti fìlà 100
Olúkó yóò koo ni ìwà reree
Àti èkó ìbòwò fún òbí
[edit] Ta’aziyar Haladu Farin Tsoho
Allah na roke ka, albarkar Manzon Allah,
Allah ya jikan Haladu,
Dan Barau bijimin fama.
Allah ya ji kan Haladu,
Ga dan ya mutu ya huta, 5
To Allah ya ji kan Haladu,
Allah kyauta makwancinai
A zamaninai shi Haladu,
Ya shirya halin kirki,
Mahaifa sun sahida, 10
Abokai sun shaida,
Haka kowa ya shaida,
Ya shuka abin kirki,
Akwai hakuri a wajen Haladu,
Sannan ko akwai da ‘a 15
Bay ya rainin kowa ko
Bai rainako ko wajen kome,
Don ya shuka abin kirki,
To Allah na roke ka,
Albarkar Manzon Allah, 20
To Allah kyauta wakwancin sa,
Nai kira ga aminanchi
Nai kira ga abokanshi,
Nai kira ga mutanensa,
Dan Allah don lillahi 25
Wanda duk dai yai sallah,
Ya tune da kushewatai
Allah na roke ka,
Albarkar Manzon Allah,
Ka agaze wa bayinka, 30
Don Haldu farin tsoho
Tarihi ya nuna,
Hijirar manzon Allah,
Barinsa ga Makka dada,
Zuwan so Madina dada, 35
Mutan madina sun karbe shi,
Wanda ya sauke shi,
Shi ne Haladu farin tsoso
Taron jama ‘ar Allah,
In Allah ya ba ka, 40
In ya sa ka samu,
Ka aikate alheri,
Kamar Haladu farin tsoho
Da sanin darajar jama ‘a,
Kowan mutu ya huta, 45
Ta Allah kyauta makwancinmu,
Allah kyauta makancina
Idan yau dai mu ne,
Gobe ko ba mu ba,
Mu tuntuni mun sheda, 50
Sai mu bar wa ‘ya ‘yanmu,
Su su bar wa jikoki
Don tarihi ya nune,
Mutuwa rigar wannan
Mutuwa rigar wancan, 55
Mutuwa rigar wanna,
Mutuwa rigato ce,
Da da hali Wallahi,
Tawa ko ai da na tube,
Ku tabbartar da na kyautar, 60
Ba hali
In ka je kabari malam,
In ka aikata makirci,
Makircin ne zai bi ka,
In ka aikata kinibibi 65
Kinibibin ne zai bi ka,
In ka aikata ha ‘inci
Ha Shari ne sai bi ka
In ka aikata ma sharri
Ha ‘incin ne zai bi ka, 70
In ka aikata ma sharri
To sharrin ne zai bi ka,
In ka aikata alheri,
Alherin ne zai bi ka,
Ranar ba ni ne wane, 75
Ta sai hali kuma sai salla,
Sai abin da ka aikatar
Allah ga kayanka
Allah ga kayanka
Ka kyauta makwancimu 80
Allah kyauta makwanicina
Da da farkon zamani
Tarihi ya nuno,
Haramun ce ka gudu
Tana ta biyan jama ‘a 85
Jama ‘a kuma na ta gudu
Sun cire kuma hularsu,
Suna fadin sai sun tsira,
Yanzu ko Wallahi,
Haramum ce ka gudu, 90
Suna to biyarta dada,
Sune fadin sai sun kamo
Allah ga kayanka,
Albarkar Manzon Allah,
Ka kyauta makwancinmu, 95
Allah kyauta makwancina
Idan ka haifi danka
Ka ka ai shi gun karatu
Ika I sa koyariwa kowanikuna
Ika I sa I yanke farce 100
Sai sa I wanke rigahulada wando
I je aji ka gane
Sannan I zan karatu
[edit] Condolence Song for Late Haladu Farin Tsoho
Go I pray you for the sake of your prophet
May you forgive Haladu
The son of Barau, the strong man
May God forgive Haladu
May he have peace in his grave 05
May God forgive Halladu
May God protect his grave
When Halladu was alive
He has a good character
His parents are witness 10
His friends are witness
Everbody are all witness
That he has planned good and did good
Halladu was patient and humble
He has a good behaviour 15
He does not look down upon anybody
He does not disrespect anybody
God, l implore you
Blessings of your prophet
May God protect his grave 20
I am calling on his associates
I am calling on his friends
I am calling on his relatives
For God’s sake
Whoever want to pray 25
Should remember the dead
God I implore you
For the sake of your prophet
God help us that are left behind
Because of Halladu 30
History has shown
Movement of the prophet
When he left Mecca
For Madina
People in Medina accepted him 35
People who accepted him
Halladu is the type
Assembly of God’s people
If God bless you
If you have 40
Do good
Know the people’s right
Like Halladu
The dead are resting
May God protect our graves 45
May God protect my grave
If we are today
Tommorrow we are not
We should always rember the fact
We must leave all for our children 50
The children too must leave for their children
Because history has shown that
Death is a must for this
Death is a must for that
Death is a must for this 55
Death is a grown
If it is possible
I would remove mine
And dash it out
It is not possible 60
When you go to the grave
If you were crafty on earth
It is craftiness that will follow you you
If you do the work of eves dropping
It is evesdropping that will follow you 65
If you do fraud
It is fraud that will follow you
If you do justice
Justice shall follow you
If you handwork is straight 70
Straightness shall follow you
If you do good
Goodness shall follow you
That day is not mine
Except your character and your worship 75
Except what you did.
God, see your people
God see your people
Protect our graves
Like before 80
Protect my grave
History has shown
Bad behaviour please go away
It is always following people
People are running away 85
They remove their caps
They said they have escaped
Now it is true
The prohibited is running
People too are running 90
After the prohibited
They said they have caught up with it
God, see your people
Blessing of your prophet
Protect our graves 95
God, protect my grave
Because, when we give birth to a child
We will take him to the school
The teacher will be teaching everyday
How to cut fingernails 100
How to wash shirt, trouser and cap
The teacher will teach him good habits
And how to respect parents.
[edit] Orin Ìdàrò fún Olóògbé Haladu Farin Tsoho
Ọlorun mo gbadura nitori ojise re
Forijin Haladu
Omo Barau, alagbara okunrin
Ki Ọlorun forijin Haladu
Ki o sun-un re 05
Ki Olórun foríjin Haladu
Kí Olórun dáàbòbó ibojì re
Nígbà ti Haladu wà láyé
Ó ní ìwà rere
Obi rè jé elerii 10
Àwon òré rè jé elérìí
Gbogbo ènìyàn je elérìí
Pé ó gbèrò rere, ó sì se rere
Haldu ni suuru àti ìteríba
Ó ní ìwà rere 15
Kì í fojú tenbelu enikeni
Kì í se àfojúdi sí eníkeni
Olórun, mo bè ó
Nítorí òjísé re
Kí ó dáàbòbo ibojì rè 20
Mò ń pe gbogbo alábàárò
Mo ń pe gbogbo òré
Mò ń pe àwon ará ilé rè
Nítorí Olórun
Enikéni tó bá fé gbàdúrà 25
Kí ó rántí Haladu
Olórun mo bè ó
Nítorí òjísé re
Ran awa tí ó kù sáyé lówó
Nítorí Halladu 30
Ìtàn ti fi hàn
Irinajo òjísé ńlá
Nígbà tí ó kúrò ní Mecca
Lo sí Mèdínà
Àwon ará Medina gbà á 35
Irú àwon tí ó gbà á
Ni Halladu jé
Gbogbo mùtúmùwà
Ti Olórun bá bù kún yin
Tí e ni orò 40
Ki e si mo ètò ènìyàn
Bi i ti Haladu Farin Tsoho
Àwon òkú ń sinmi
Ki Olórun dáàbòbo ibojì wa
Kí Olórun dáàbòbo ibojì mi 45
Bí a bá wa lónìí
Òla, a kò sí mó
A gbódò máa ranti pé
A gbódò fi ayé sílè fun àwon omo wa
Àwon náà gbódò fi sílè fómo 50
Nítorí ìtàn fi han pe
Dandan ni ikú fun èyí
Dandan ni fún iyen
Dandan ni fún èyí
Aso ni ikú 55
Tí ó bá se é se
N bá ti bo aso ikú tèmi sonù
N bá ti bùn elòmìíràn
Sùgbón, ala ti ko le se ni èyí
Ọgbeni, nigba ti o ba file bora bí aso 60
Bi o ba jé arékérekè nílé ayé
Àrékérekè ni yo tè lé o
Tí o bá jé òfófó láyé
Òfófó ni yóò tè lé o
Bí o bá jé ońijìbìtì láyé 65
Jìbìtì ni yóò tè lé o
Tí o bá jé aláìsègbè láyé
Àìsègbè ni yóò tè lé o
Bí isé owo re bá gún láyé
Ònà re yóò gún lorun 70
Bí o bá se rere nílé ayé
Rere ni yóò tèlé o
Lójó yen kò sí pé ènìyàn pàtàkì ni mi
Àfi iwa àti ìsìn re
Àfi ohun tí o gbáyé se 75
Olórun wo àwon ènìyàn
Olórun wo àwon ènìyàn re
Dábòbo ibojì wa
Bí i télè
Dáàbòbò ibojì mi 80
Ìtàn ti fi hàn
Iwa buruku jòwò maa ló
Ó sàbá máa ń tè lé àwon ènìyàn
Àwon ènìyàn ń sá lo
Wón sí fílà lórí 85
Wón ni àwon ti sá àsálà
Nísinsinyìí, òtító ni
Nnkan èèwò ń sáré
Àwon ènìyàn náà ń sáré
Tè lè e lèyìn 90
Wón ni àwon ti lé e bá
Olórun wo àwon ènìyàn re
Ìbùkún òjísé Olórun
Dáàbòbò ibòjì wa
Olórun, dáàbòbò ibòjì mi 95
Nítorí tí a bá bí omo
A ó mú un lo sí il ilé ìwé
Olúkó yóò máa ko o lójoojúmó
Bí a se ń gé èékánná
Bí a se n fo èwù sòkòtò àti fìlà 100
Olúkó yóò koo ni ìwà reree
Àti èkó ìbòwò fún òbí