Ibo
From Wikipedia
Ibo
Èdè Ìgbo
Won ń so èdè yìí ní ilè Náíjíríà. Àwon tí wón ń so ó jé mílíònù méjìdìnlógún, pàápàá jùlo ní ìlà gúsù, won mo ón si Bíafra. Ó jé èdè Olóhùn gégé bi èdè Yorùbá. Ohùn ni a fi máa ń dá àwon èka èdè rè mò. Wón fi akosile Roammanu ko o sile. John Gold Smith sì lò mó gégé bí àpeere.