Ifon Omimah
From Wikipedia
IFON OMIMAH
Ifón omímà, níbè ni mo ti wá
Ìyá yá wo mí ya wò pèlú bàbá ibè na ń gbé
Ayé ìgbálájá mibá 255
Ayé ìgbàlàmugbàgà
Sàmùsamu là í jògèdè
Á ma i rógogo leyin adìye
Àwon tó jé ti bàbá mi
Wón ń so péfón ni mo ti wá 260
Awon to je ti yeye mi
Wón ń so pówoòwo ni won bi mi
A kìí lapaa baba
Ká mama ni ti Yeye
Tòtúntòsi gbebiti mo mi leyin 265
Ke sá ti gbémi déle owó
È ye mò yé e kú ràńsè o
È mà júsé mi ní bà mi
Ona ma se …
Òjá o mókùn olà o 270
Tóbá mo ìbá n ja
Kìí sènìyàn ló gbé mi dépò mi o
Edumare ni se
Òbàolúwa lo gbé wa dépò wa a
Kìí se sé owó omo eda kankan 275
Ota o mokun ola o
Boba mo iba ti ja
Ajétúwongbé, oluwa lo fun mi o
Kìí sowó omo eda kankan
Omolayole omolayole 280
A mawa
Ègbè: omolayole omolayole
Lílé: omolayole
Ègbè: omolayole
Lílé: O tete re mo loju ma ra soke 285
Ègbè: omolayole
Lílé: omolayole
Ègbè: omolayole
Lílé: omolayole
Ègbè: omolayole 290
Lílé: Amama
Amama