Ijo
From Wikipedia
Ijo
Ijaw
Èdè Ijo
Àwon tí wón ń so èdè ìjoid ni Ijo (Ijaw) àti Defaka ti Niger Delta ní ilè Nàíjírà. Àwon tí wón ń so ó jé mílíònù méjì dín ní pónti méta. A lè rí won ní gúsù ilè Nàíjírà. Èka Ijo ni to bi èdè Ìjo mésàn-án
Àwon tí wón ń so Ijo ti tóbi jù jé mílíònù kan.