Jerry Ore
From Wikipedia
JERRY ÒRÈ
Èrò mi ròrè o
E kí Abdul mi 40
Òbà Àkókó nilé
Abdul mi òkan ni
Èrò tó mí ròrè o
E kí Jerry fún mi lórè o
Eléwéolà lórè o 45
Èrò bá mi kí Jerry mi
Uròbò nile,
Baba Túndé, òkan ni
Lílé: Onílù mi pàlù dà o
Ọmo Jerry fé jó 50
Ègbè: Onílu mì pàlùdà o
Áwa lólòde wa
Lílé: Onílù mi pàlùdà o
Àwa lólòde o
Ègbè: Onílù mi pàlùdà o 55
Lílé: Onílù mi pàlùdà o
Dádìmatà fé jó
Ègbè: Onílù mi pàlùdà o
Awa lólòde wa
Lílé: Ewu iná kì í pàwòdì o 60
Dádìmatà ó kú ewu
Ègbè: Onílù mi pàlùdà o
Àwa lólòde wa
Lílé: Onílù mi pàlùdà o
Àwa lólòde wa 65
Sáwa lolòde
Ègbè: Onílù mi pàlùdà o
Àwa lólòde wa
Lílé: Èèkómilà waa jo
Awá lolòde wa o 70
Ègbè: Onílù mi pàlùdà o
Àwa lólòde wa
Lílé: Ee onilu mi pàlùdà o
Oòkémilà wáá jó
Ègbè: Onílù mi pàlùdà o 75
Àwa lólòde wa
Lílé: Find your way wa jo
Onílù mì pàlùdà o
Ègbè: Ee onilu mi pàlù da o
Find your way ló ń jó