Luba II
From Wikipedia
LUBA
Orúko mìíràn tí a le fun Luba ni Chiluba tabí Taliluba. Ó jé òkan nínú àwon èka èdè ni Luba –lulua tí ó wà ní orílè èdè Bantu.
Ní ìbèrè pèpè, ekùn ìlú kasanji ni a ti máa n so èdè yìí àwon tí ó sì ń so ó dín díè mílíónù méfà àti ààbò. Ní Lubà-Kasai won le díè ni mílíònù kan àti àbò ni Luba-Katanga won kò ju òke kan lo ní Kangok; wón din díè ní òké kan ni Hemba; won le díè ní òké méjì ni Sanga, wón sì le díè ní òké kan ní Lwatú.