Mo ti to Jesu wo
From Wikipedia
MO TI TÓ JÉSÙ WÒ
Lílé: Mo ti tó Jesù wo, ó ma dùn ju oyin lo
Ójójumò ni yo ma dùn si Halelúyà 325
Ègbè: Mo ti tó Jesù wo, ó ma dùn ju oyin lo
Ójójumò ni yo ma dùn si Halelúlà
Lílé: Mo ti tó Jesù wo, ó ma dùn ju oyin lo
Ójójumò ni yo ma dùn si Halelúyà
Ègbè: Mo ti tó Jesù wo, ó ma dùn ju oyin lo 330
Ójójumò ni yo ma dùn si Halelúyà
Lílé: Afójú laláìgbàgbó torí won kò mosé rOlúwa
Mo ti mosé Olúwa n ó forìn mi yìn o lógooo
Ègbè: Mo ti tó Jesù wo, ó ma dùn ju oyin lo
Ójójumò ni yó ma dùn si Halelúyà 335
Lílé: Eni bá more Jésù ó ye kó lè yin logo
Èmí more Jésù n ó ma yìn o títí láé
Ègbè: Mo ti tó Jesù wo, ó ma dùn ju oyin lo
Ójójumò ni yo ma dùn si Halelúyà
Lílé: Baye n koja borun n kojá 340
Ohun gbogbo le yi padà
Òrò Olúwa ko ni yi padà titi lae
Ègbè: Mo ti to Jesu wo,
Ó dùn ju oyin lo
Ojoojúmó ni yoo ma dùn si Hallelúyàh 345
Lílé: Òlorúnfúnmi Johnson omo Òdùyemí
Eni t’Ólórun mi da n o ma yin o logo
Ègbè: Mo ti tó Jesù wo, ó ma dùn ju oyin lo
Ójójumò ni yo ma dùn si Halelúyà
Lílé: ‘Chairman Managing Director’ 350
Òdúyemí ‘Nigeria Limited,’
E gbÓlúwa ga kò sóba méjì bí Olúwaa
Ègbè: Mo ti to Jesu wo,
Ó dùn ju oyin lo
Ojoojúmó ni yóó ma dùn si Halelúyàh 355
Lílé: Afójú laláìgbàgbó torí won kò mosé rÓluwa
Mo ti more Olúwa
N ó ma yin o títí láé
Ègbè: Mo ti to Jesu wo,
O dùn ju oyin lo 360
Ojoojúmó ni yóó ma dùn si Halelúyàh
Lílé: Mímó mímó mímó mímó mímó mímó mímó
Ni yóó ma wà titi lae
Orúko Jésù
Ègbè: Mímó mímó mímó mímó mímó mímó 365
ni yóó ma wà títí láé
Lílé: Mímó mímó mímó mímó mímó mímó
Ni yóó ma wà titi lae
Ni yó ma titi lae
Omoléyìn Jésù 370
Ègbè: Mímó mímó mímó mímó mímó mímó
Ni yóó ma wà titi lae
Lílé: Òjísé Jésù
Ègbè: Mímó mímó mímó mímó mímó mímó
Ni yóó ma wà títí láé
375
Lílé: Àgbàlá Jésù
Ègbè: Mímó mímó mímó mímó mímó mímó
Ní yóó ma wà títí láé
Lílé: Ibi tí Jésù bá wà
Ègbè: Mímó mímó mímó mímó mímó mímó 380
Ni yóó ma wà títí láé