Ogba ni wa loju Olorun
From Wikipedia
Duka Dangantakarku Daida (Ogba ni wa loju Olorun))
Contents |
[edit] DÉÉDÉÉ NI WA NI OJÚ OLÓRUN
Ati eni to ni ati aláìní
Bakan naa ni won
Olorun lo so bee
Kì í se emi
Ká so pé èmi ni mo so béè 5
E lè fi ìdí re múlè pé iró ni mo pa
Ìwo tí o ní ohun pupo
Tí o bá kó ogbòn ilé
Inú eyo kan ni ó máa sùn
Àti ní inú yàrá kan péré 10
Ní orí ibùsùn kan soso
Bákan náà ni pèlú eni tí kò ní nnkan kan
Yóò sùn nínú ilé kan
Ní inú yàrá kan
Ní ègbé kan 15
Sùgbón bi ilè bá mó
Gbogbo yin a di bákan náà
Apere kékeré mìíran fùn o ni pé
Ìwo tí o ní ohun púpò
Ti o ba rò pe o ni ohun púpò 20
O kò dé fìlà méwàá léèkan soso
Sí orí re
Bí béè kó tí wón bá rí o
Wón a ní o ti ya were
Nítorí náà o ní láti dé fìlà kan
25
Béè ni tálìkà tí kò ní nnkan kan
Yóò dé fìlà kan sí orí rè
Tí ó bá lówó rè
Tí o bá wòó dáradára
Níhìn-in bakan náà ni wa 30
Àpeere mìíràn
Agogo owó tí a rà ní egbèrùn méfà náìrà
Àti òmíràn tí a rà ní náírà méta
Tí àwon méjéèjì bá so àkókó déédéé
Tí a bá fé fún won lórúko 35
Agogo ni a ó pe gbogbo won
N ó fùn o ni àpeere mìíràn
Wàrà ti o to naira meta
Ati òmìíràn to je ogbon kobo
Tí o bá wo àwò won daradara 40
funfun ni gbogbo won
Ó ye kí o yé ìwo Lánínntán pé
Tí o bá rò pé o ni òpò ohun gbogbo
O kò le wo bata méwàá pò léèkan soso
Sí esè re 45
Nitori ti a bá rí o béè
Wón a ní ó ti ya wèrè ni
Nítorí náà o gbódò wo bàtà kan péré
Eni tí kò ní nnkan kan náà
Yó wo eyo bàtà kan 50
Tí ó bá ni owó rè
Nítorí náà, ògbéni, tí o bá ronú jinlè
Kò sí ìyàtò kan láàrin ìwo àti onítòhún
Ìwo lánínntán gbódò jé kó yé o
N ó fun àpere mìíràn 55
Ọlórun atóbijù
Kó ní nnkan se pèlú ilé re
Kò ní n nkan se pèlú òrò re
Èrò okan re ló je e lógún
Béè náà ni pèlú eni tí kò ni nnkankan 60
Ọlórun aláàánú
Ọkàn re ló je e lógún
Nítorí náà Ògbèni tí ó ba wò ó daradara
Bákan náà ni yín níwáju Ọlórun
Ìwo lánínntán gbódò mo èyí 65
Àpeere mìíràn nìyí
Ní ojó ti ikú bá dé
Òpá aso funfun márùn-ún
Ni won ó fi dì ó
Won yóò si gbe o sínú sàréè kan 70
Rántí won kò ní gbé méwàá
Nítorí pé o ní òrò
Nínú re won yóò bo o mólè
Béè ni fún òtòsì
Ní ojó ìpàpòdà 75
Òpá aso funfun márùn-ún
Ní wón yóò fi dì í
Wón yóò gbé sàréè kan
Wón ko ni gbé méwàá
Nítorí kò ní nnkan kan 100
Nítorí náà tí o bá ronú jinlè
Lórí eléyìí o kò yàtò, sí òun
Ìwo láninntán gbódò mò pé
Níwòn ìgbà tí o bá ní orò
Tí èrò re si je rere sise 105
O ran gbogbo ènìyàn lówó
O se àánú fún gbogbo ènìyàn
O fa awon ènìyàn lówó sókè
Ní ojó ìpàpòdà
Dandan ni kí inú re kó dùn 90
Béè ni inú àwon omo tí o fi sílè yóò dùn
Bakan naa, bí Olòrun bá fún o ní orò
Tí èrò re si jé buruku sise
O kò ran enikéni lówó
O maa n dójú ti ènìyàn 95
O maa n yan ènìyàn je
Ni òòrè kóòrè
Àwon ilé àti àwon ìyáwó re
Pèlú àwon mótò re
Títí de ori àwon omo rè yóò di òfo 100
Àwon ìyàwó re yóò di ofo
Àwon okò re yóò di ofo
Bí àsìkò ikú bá tó
Ìwo pàápàá á wá paré
Lójó náà ìwo ati asán 105
Ni ogboogba
Olórun oba tí a ń wojú rè
Ó dá Lárúbáwá
Ó dá àwon Géèsì
Ó dá àwon ará Améríkà 110
Ó dá àwon ará India
Olórun oba tí à ń wò lójú
Ó dá gbogbo èyí fún ayé rí
Jé kí n fún o ni ìmòràn kan
Ó dá àwon ará ‘Ghana’ 115
Ó dá àwon ará ‘Ethiopia’
Ó dá Nàíjíríà wa
Gbogbo wa dúdú
Olórun oba tí à ń wó lójú 245
Ó se èyí kí gbogbo ènìyàn lè rí i 120
Sùgbón àti olówó àti otòsì
Bákan náà ni gbogbo yín
Olórun ló so bé
Kì í se mo so bé è 250
Tí o bá se èmi ni mo so bé è
O lè jà mí níyàn
[edit] DUKA DANGANTAKARKU DAIDAI
Amma mai akwai da babu,
Duka dangartakarku daidai,
Allah yake fadar haka,
Ba ni nake fada ba,
Da ni nake fadar haka,
Da sai ku karyata ni 5
Kai mai akwai ka gene,
Idan kai gida talatin
Cikin guda za ka je ka kwana,
A daki guda kakan kwan,
A kayin gado guda dai, 10
Haka nan wanda bai da kome,
Gida guda yakan kwan,
A daki guda yakan kwan,
A gefe guda yakan kwan,
To in gari ya waya, 15 To nan duka dangantakarku daidai
In ba ku dan misali,
Kai mai akwai ka gane,
In kana takar akwai ne)
Ba ka sanya hulo gomo 20
A kanko kai dai,
Ai da an gano ka,
Sai a ce “Wane ya tabu”,
Sai dai ka sa guda dai
Haka nan wanda bai da kome, 25
Shi ma ya so gude dai,
Matukar in yana da hali,
To mallam idan ka duba,
Ta nan duka dangantakarku daidai
In ba ku dan misali, 30
Da agogon jake talatin,
Da agogon sule talatin,
In wannan ya ba da loto daidai,
In za a dai kira su
Sai ka ji sunansu duk agogo 35
In ba ku dan misali,
Da nonon sule talatin,
Da nonon kwabo talatin,
In za ka dai zuba,
Ai sai ka ga duk dai farinsu daidai 40
Kai mai akwai ka gane,
In tana takamar akwai ne,
Ba ka sanya takalmi goma,
Kafar ka kai dai,
Ai da an gano ka, 45
Sai a ce Ga mahaukaci nan.”
Sai dai ka sa gudo dai,
Hakanan wanda bai da kome,
Shi ma ya sa guda dai,
Matukar in yana da hali, 50 To mallam dan ka gane,
Ta non duka dangartakarku daidai
Kai mai akwai ka gane,
In ba ka dan misali,
Shi Allah Huwallazina, 55
Bai aiki de duk gidanka,
Bai aiki da arzikinka,
Sai dai da zuciya fa, Haka nan wanda bai da kome,
Allah Huwallazina, 60
Sai dai da zuciyatai,
Shi Malam idan ka duba,
Ta nan duka dangartakarku daidai
Kai mai akwai ka gane,
In ba ka dan misali,
65
Ran komuwa ga Allah,
Yadi biyar fa dai,
A ciki za a nannade ka,
Rami guda a kan tona,
Ka tuna ba ab tona goma, 70
don wai kana da hali,
A ciki za a turbude ka,
Haka nan wnade bai da kome,
Ran komuwa ga Allah,
Yadi biyar fari dai, 75
Ciki za a nannada shi,
Rami guda shan tona,
Ka tuna ba a tona goma,
Don wai fa bai da kome,
To Mallam idan ka duba, 80
Ta nan duka dangartakarku daidai
Kai mai akwai ka gane,
(In mai akwai ka gane),
In muddin kana da shi ne,
Kai taimako ga kowa, 85
Ka taimakawa ga kowa,
Ka agazawa kowa, Ran komuwa ga Allah,
Wallahi ka ji dadi,
Bayanka sun ji dadi, 90
In muddin kana da shi ne,
Burinka dai a bata,
Ba ka taimako ga kowa,
Burinka cin mutumci,
Ko burinka cin amana, 95
Mallam a kwan a tashi,
Gidaje gami da mata,
Sannan gami da mota,
‘Ya ‘ya su zo su kare,
Mata su zo su kare, 100
Mota ta zo ta kare,
Ka ga ran komuwa ga Allah,
Kai ma ka zo ka kare,
Ka ga ranar da kai da babu,
Ka ga Wallahi babu bambam 105
Allah Huwallazina,
Ya yi Larabawa,
Ya yi Ingilishi
Yay yo mutan “America”
Ya yi Hindiyawa, 110
Allah Huwallazina,
Yai haka domin mu gane juna,
In ba ku dan misali,
Allahu ya yi “Ghana”
Yai “Ethopia” ai 115
Yai Nijeriyarmu mu ma,
Ga mu duk hakake,
Allah Huwallazina,
Yai haka domin mu gane june
Amma mai akwai da babu, 120
Duka dangartakarku daidai,
Allah yake fadar haka,
Ba ni nake fada ba,
Da ni nake fadar haka,
Da sai ku karyata ni 125
[edit] All are equal before God
Both the rich and the poor
They are all equal
It is God that say this
I am not the one saying it
Assuming it is my statement 5
You can prove me wrong
You the owner of plenty
If you build thirty houses
You will be sleep in only one
And in only one room 10
And just on one bed,
The same thng applies to the poor
He will sleep in one house
In one room
And at one corner 15
But when the day breaks,
You all become the same thing
Another example for you is that
You the owner of plenty
If you think you have abundance 20
You cannot put on ten caps
On you head alone
Or else, if they see
They will say you have run mad
So you have to put only one cap 25
Also, the poor man who has nothing
Will also put only one cap
If he can afford it
So if you look at it well
Here, you are all the same 30
Another simple example
A wrist watch tht cost six thousand naira
And another that cost three naira
If each of them gives time accurately
If you are going to name them 35
Then you will call of them watch
I give yet another eample
Cow milk worth 30 shillings
And another tht cost 30 kobo
If you observe their colour, 40
They are all white in colour
You the rich should understand that
If you think that you have everything in excess
You cannot put on 10 pairs of shoes at once
On your own leg alone 45
Because once you are spoted like that
They will say you have run mad
So, you must put on one pair only
The one who has nothing also
Will put on one pair only 50
If at all he can afford the one pair
So if you look at it well
You are all equal
You the rich should understand
I will give you another example 55 God the greatest
Does not work with your house
Nor does He Work with your wealth
He works only with what is in your mind
The same thing applies to the poor 60
God the merciful
He works with his heart
So, if you look at it well
You are all equal before God
You the rich should know this 65
This is another example
On the day of death
Five yards of plain cloth
Is what they will use to wrap you
And they will put you into one grave 70
Remember, they will not dig ten
Simply because you have wealth
Inside they will cover you
Equally, the poor man
On the day of retuning to God
75
Five yards of plain clothe
Is what they will use to wrap him?
They will dig one grave
They will not dig ten
Because he has nothing 80
So, if you think well
Here, you are the same thing
You the rich should know that
So long as you posses wealth
And your intentions are towards planning good 85
You help every body
You assist every body
You lead people to progress
On the day of retuning to God
Surely you will be happy 90
And the children you left behind will be happy
Equally, if God has given you wealth,
And your intentions are always towards eveil
You don’t help anybody
You always disgrace people 95
You always cheat people
Day in day out,
Your houses and your wives
Plus your vehicles
Even the children will be nothing 100
Your wives, will be nothing
Your vehicles will be nothing
When it is time for you to retun to God
You also will become nothing
On that day, you are nothing 105
Are equal
God that we are looking up to
He created Arabs
He created the English
He created the Americans 110
He created Indians
God that we are looking up to
He created all the above for people to see
Let me give you advice
He crated the Ghanians 115
He created Ethiopians
He created our Nigeria
All of us black
God that we look up to
He did that so that all can see 120
But the poor and the rich
All of you are the same
God say so
It is not me that say so
If it is me that say so 125
You can challenge me.
[edit] DÉÉDÉÉ NI WA NI OJÚ OLÓRUN
Ati eni to ni ati aláìní
Bakan naa ni won
Olorun lo so bee
Kì í se emi
Ká so pé èmi ni mo so béè 5
E lè fi ìdí re múlè pé iró ni mo pa
Ìwo tí o ní ohun pupo
Tí o bá kó ogbòn ilé
Inú eyo kan ni ó máa sùn
Àti ní inú yàrá kan péré 10
Ní orí ibùsùn kan soso
Bákan náà ni pèlú eni tí kò ní nnkan kan
Yóò sùn nínú ilé kan
Ní inú yàrá kan
Ní ègbé kan 15
Sùgbón bi ilè bá mó
Gbogbo yin a di bákan náà
Apere kékeré mìíran fùn o ni pé
Ìwo tí o ní ohun púpò
Ti o ba rò pe o ni ohun púpò 20
O kò dé fìlà méwàá léèkan soso
Sí orí re
Bí béè kó tí wón bá rí o
Wón a ní o ti ya were
Nítorí náà o ní láti dé fìlà kan
25
Béè ni tálìkà tí kò ní nnkan kan
Yóò dé fìlà kan sí orí rè
Tí ó bá lówó rè
Tí o bá wòó dáradára
Níhìn-in bakan náà ni wa 30
Àpeere mìíràn
Agogo owó tí a rà ní egbèrùn méfà náìrà
Àti òmíràn tí a rà ní náírà méta
Tí àwon méjéèjì bá so àkókó déédéé
Tí a bá fé fún won lórúko 35
Agogo ni a ó pe gbogbo won
N ó fùn o ni àpeere mìíràn
Wàrà ti o to naira meta
Ati òmìíràn to je ogbon kobo
Tí o bá wo àwò won daradara 40
funfun ni gbogbo won
Ó ye kí o yé ìwo Lánínntán pé
Tí o bá rò pé o ni òpò ohun gbogbo
O kò le wo bata méwàá pò léèkan soso
Sí esè re 45
Nitori ti a bá rí o béè
Wón a ní ó ti ya wèrè ni
Nítorí náà o gbódò wo bàtà kan péré
Eni tí kò ní nnkan kan náà
Yó wo eyo bàtà kan 50
Tí ó bá ni owó rè
Nítorí náà, ògbéni, tí o bá ronú jinlè
Kò sí ìyàtò kan láàrin ìwo àti onítòhún
Ìwo lánínntán gbódò jé kó yé o
N ó fun àpere mìíràn 55
Ọlórun atóbijù
Kó ní nnkan se pèlú ilé re
Kò ní n nkan se pèlú òrò re
Èrò okan re ló je e lógún
Béè náà ni pèlú eni tí kò ni nnkankan 60
Ọlórun aláàánú
Ọkàn re ló je e lógún
Nítorí náà Ògbèni tí ó ba wò ó daradara
Bákan náà ni yín níwáju Ọlórun
Ìwo lánínntán gbódò mo èyí 65
Àpeere mìíràn nìyí
Ní ojó ti ikú bá dé
Òpá aso funfun márùn-ún
Ni won ó fi dì ó
Won yóò si gbe o sínú sàréè kan 70
Rántí won kò ní gbé méwàá
Nítorí pé o ní òrò
Nínú re won yóò bo o mólè
Béè ni fún òtòsì
Ní ojó ìpàpòdà 75
Òpá aso funfun márùn-ún
Ní wón yóò fi dì í
Wón yóò gbé sàréè kan
Wón ko ni gbé méwàá
Nítorí kò ní nnkan kan 100
Nítorí náà tí o bá ronú jinlè
Lórí eléyìí o kò yàtò, sí òun
Ìwo láninntán gbódò mò pé
Níwòn ìgbà tí o bá ní orò
Tí èrò re si je rere sise 105
O ran gbogbo ènìyàn lówó
O se àánú fún gbogbo ènìyàn
O fa awon ènìyàn lówó sókè
Ní ojó ìpàpòdà
Dandan ni kí inú re kó dùn 90
Béè ni inú àwon omo tí o fi sílè yóò dùn
Bakan naa, bí Olòrun bá fún o ní orò
Tí èrò re si jé buruku sise
O kò ran enikéni lówó
O maa n dójú ti ènìyàn 95
O maa n yan ènìyàn je
Ni òòrè kóòrè
Àwon ilé àti àwon ìyáwó re
Pèlú àwon mótò re
Títí de ori àwon omo rè yóò di òfo 100
Àwon ìyàwó re yóò di ofo
Àwon okò re yóò di ofo
Bí àsìkò ikú bá tó
Ìwo pàápàá á wá paré
Lójó náà ìwo ati asán 105
Ni ogboogba
Olórun oba tí a ń wojú rè
Ó dá Lárúbáwá
Ó dá àwon Géèsì
Ó dá àwon ará Améríkà 110
Ó dá àwon ará India
Olórun oba tí à ń wò lójú
Ó dá gbogbo èyí fún ayé rí
Jé kí n fún o ni ìmòràn kan
Ó dá àwon ará ‘Ghana’ 115
Ó dá àwon ará ‘Ethiopia’
Ó dá Nàíjíríà wa
Gbogbo wa dúdú
Olórun oba tí à ń wó lójú 245
Ó se èyí kí gbogbo ènìyàn lè rí i 120
Sùgbón àti olówó àti otòsì
Bákan náà ni gbogbo yín
Olórun ló so bé
Kì í se mo so bé è 250
Tí o bá se èmi ni mo so bé è
O lè jà mí níyàn