Ole
From Wikipedia
Wakar Malalaci (Ole)
Contents |
[edit] ÒLE
Ọlórun oba atóbijù
Eni tí kò láfijo
Ti fi òle sépè
O ti saata òòrayè
Eni tí kò ni isé kan 05
Nítorí òle
Ọlórun ti so pé
Bí a bá n se ìtore àánú
Ọle kò gbodo pín níbè
Eni tí kò sisé kan 10
Tí kì í bá se ti òle síse
Eran dídà wà
Oko dídá wà
Eniyan tilè le máa ge èékánná
Tábí ko sa tata kó sì tà á 15
Gbogbo ìwònyí isé ni
Tó kò tí kò yan òkankan láàyò
Nítorí èmí ìmélé
E máse dààmú nítorí òle.
Nitorí òle ènìyàn 20
Jé ègo àti òpònú ènìyàn
Ise rè kò ju kó paró fún àwon ènìyàn
Tàbí kó má a se arírébánije
E ó bá won ní ilé onílé
A ní ìyàwó mi ti bimó 25
Kí o bàà le fún un ní ohun tí o ni
Tàbí kí e bá a nílé elòmíràn
A ní mo fé gbéyàwó
Kí ó le fún un ni ohun tí ó ní
Bi o bá fún un lówó díè 30
E ó rí i pèlú obìnrin àsìkò
E ó ri i nibi won ti ń ta káàdì
Tàbí ní ilé tété
Ègo, òpònú
Tí kò ní isé kankan 35
Ó ye ká lé òle dànù
Ó ye ká fi bú
A gbódò kórira onímèélé
Ègò ènìyàn tí kò ní èrò
Ègò, gbera nílè lo sisé
40
Èda tí kò wúló fún nnkan kan
Mo búra pé Nàìjíríà ti òde ònìí
Koja ká jókòó kalè láìní isé
A ti bá àìmòkan mòkàn jà
A ti gbógun ti èmí ìmélé 45
Ki olorun fi òle bú
Tí kò ní isé kankan
[edit] WAKAR MALALACI
Allah mafi girma
Wanda babu iri nai
Ya la’anci malalaci
Ya tsine malalaci
Wanda bai sannar konne 5
Anne shi ko malalaci
Sanna Allah ma ya ce
Ko Zakka in an fidda
Kar a bai wa malalaci
Wanda bai sanaar kome 10
Amma ban da malalaci
Ga kiwon shanu
Ga sannar noma
Ga yankan farce
Ga sanaar fara 15
Duk dai sanaa ce ai
Duka ya ki ya je ko daya
Domin mutuwar zuci
A kar ku damu da dan iska
Shi ko malalaci 20
Sofi mutumin banza
Aiknsa ya je kariya
Ko ije shi tumasanci,
Ko ka gen shi gidan wannan,
Matata ta aihu 25
Don ku ba shi abun hannunku,
Sai ka gen shi giden wancan,
Malam na son aure,
Don ka ba shi abin hannunka
In ka ba shi abin hannunka 30
Sai ka gan shi giden mata
Ko ko ke gan shi giden karta,
Ko ka gan shi gidan caca,
Wo fi mutumin banza,
Wanda bai sanaar komai 35
Mu kori malalaci
Mu tsine malalaci
Mu tsargi malalaci,
Wofi mai mutuwar Zuci,
Kai! Tashi ka je aiki, 40
Wofi mutumin banza
Najeriya wallah
Ta zarce jarman, banza
An yaki ko Jahilci
An yaki ko lalaci, 45
Allah tsine malalaci,
Wanda bai sanaar kome
[edit] The Lazy Man
Allah the greatest
The one whom there is no equal
Has cursed the lazy
Has comdemned the indolent
The one who does no trade at all 5
But for the lazy men
Even Allah has said
Even when giving out Zakat
It should not be shared with the lazy men
Who does no trade at all 10
If not for the lazy man
There is cattle rearing
There is farming
One can even be cutting nail
Or catching and trading in locust 15
All these are professions
Which he refuses to take any one
Because of weak spirit.
You should not worry with the indolent
Because the lazy man 20
Is a foolish, idiot fellow
His only work is to go and lie to people
Or go psycophancy
You find him in someones house
Saying my wife has delivered 25
So that you give him what you have
Or you find hin in another persons house
saying I want to marry
So that he gives him what he has
If you give him some money 30
You find him with women
You find him playing cards
Or at the gambling points
The foolish idiot
Who takes to no trade 35
We should send the lazy man away
We should curse him
We should hate the indolent
The foolish man without spirit or will,
Foolish, wake up, go and work, 40
The uselss human being.
Nigeria of today, I swear
Is beyond sitting indolently
We have fought ignorance
We’ve fought against indolence 45
May God curse the indolent
Who does not trade at all.
[edit] ÒLE
Ọlórun oba atóbijù
Eni tí kò láfijo
Ti fi òle sépè
O ti saata òòrayè
Eni tí kò ni isé kan 05
Nítorí òle
Ọlórun ti so pé
Bí a bá n se ìtore àánú
Ọle kò gbodo pín níbè
Eni tí kò sisé kan 10
Tí kì í bá se ti òle síse
Eran dídà wà
Oko dídá wà
Eniyan tilè le máa ge èékánná
Tábí ko sa tata kó sì tà á 15
Gbogbo ìwònyí isé ni
Tó kò tí kò yan òkankan láàyò
Nítorí èmí ìmélé
E máse dààmú nítorí òle.
Nitorí òle ènìyàn 20
Jé ègo àti òpònú ènìyàn
Ise rè kò ju kó paró fún àwon ènìyàn
Tàbí kó má a se arírébánije
E ó bá won ní ilé onílé
A ní ìyàwó mi ti bimó 25
Kí o bàà le fún un ní ohun tí o ni
Tàbí kí e bá a nílé elòmíràn
A ní mo fé gbéyàwó
Kí ó le fún un ni ohun tí ó ní
Bi o bá fún un lówó díè 30
E ó rí i pèlú obìnrin àsìkò
E ó ri i nibi won ti ń ta káàdì
Tàbí ní ilé tété
Ègo, òpònú
Tí kò ní isé kankan 35
Ó ye ká lé òle dànù
Ó ye ká fi bú
A gbódò kórira onímèélé
Ègò ènìyàn tí kò ní èrò
Ègò, gbera nílè lo sisé
40
Èda tí kò wúló fún nnkan kan
Mo búra pé Nàìjíríà ti òde ònìí
Koja ká jókòó kalè láìní isé
A ti bá àìmòkan mòkàn jà
A ti gbógun ti èmí ìmélé 45
Ki olorun fi òle bú
Tí kò ní isé kankan