Orin Igbeyawo
From Wikipedia
JAWABIN AURE (Orin Igbeyawo)
Contents |
[edit] Orin Ìgbeyàwó
Ìgbeyàwó ni mo fé sòrò lé lórí
Lákòókó, Olórun ni asíwájú gbogbo èdá
Ojise Olórun ni àtèlé
Bàbá àti ìyá ló tún tè lé e
Léyìn èyí ìgbéyàwó ló kàn 05
Tokotìyàwó e jòwó
Mo fé fun yin ní ìmòràn kan
Ètó sí gbogbo n nkan láyé yìí
Dájúdájú ètó si ohun gbogbo ní ayé yìí tí e bá rántí
Dájúdájú Ọlórun lè fi ojú fo òpò nnkan 10
Àyàfi ètò ìgbèyáwó
Tokotìyàwó, e jòwó
Tí ìjà bá wà
Nítorí Olórun e máse yára bínú
Bóyá tí e bá wadìí dáradára 15
Àwon agbótekusoféye wà ní agboolé
Ohunkóhun tí oko bá se
Á di títò fún ìyàwó
Ìyàwó kò ní se ìwádìí
Ohunkóhun tí ìyáwó bá se 20
Ádi títò fún ìwo oko lójú esè
O kò sì ni se ìwádìí
O mò pé, ó sòro láti lo ojó méje
Láìsí wàhálà kan tàbí òmíràn
Láti ibè ìgbéyàwó lè túká 25
Tí ìgbéyàwó bá di títúká
O di kí o gba olómolanke
Erù kíkó di isé re
Kíkó won lo sí ilé òbí re
Wón á fùn o ní ààyè kékeré láti kó won sí 30
Lára àwon dúkìá wònyí á bájè
Àwon kan á polúkúmusu
Àwon kan a di rádaràda
Àwon kan yóò fó
Gbogbo eyi kú se nitori aisedeede oko 35
Bee, kì í se èbi ìyàwó
Bi ko se ti alábòsí agbo ilé
Tó fé tú ohun tí Olorun tí so pò
Gbogbo wa gbódò parapò fi wón bú
Ká so fun won pé Olórun yóò dá a fún won 40
Télè iwò ìyàwó, ilé oko lo wà
O té ibùsùn re o sì sùn lórí rè
Sùgbón nísinsìnyí tí o kò ní oko mó
Bí alé bá lé won a gbé ení fún o
Gbé ení 45
Kí ìwo àti àwon omodé jo sùn
Láti ibe èrò buruku a wonú okàn re
Yóò bèrè sí to ojúlé àwon Babaláwo
Babaláwo, e jòwó e se ìrànwó oògùn fún mi
Babaláwo á gbópèlè sánlè, á ní 50
Gbogbo wàhálà wònyí owú jíje ló fàá
Inù ìkòkò àmù re fi oògùn òhún sí
Tí ìwo ìyáwó bá ti bu omi mu
Tí okó náà bù mu
Ó di dandan kí ìgbéyàwó yín túká 55
Òhun sì rè é, òdómobìnrin
Ìgbèyàwó re ti túká
E ó gbó tí obìnrin òhún á ní
Babaláwo, a ó ti se é sí
Babaláwo a ni, 60
Ònà àbáyo wa
Lo wa, àgbo funfun máarùn-ún,
Ìgàn aso funfun márù-ún
Àti pónùn méwàá
Lójú esè yanjú ìsoro re 65
Arábìnrin á ní
Gbogbo ìyen kò sòro
Yóò padà sílè
A gbé igba jáde, á tà á
A gbé àwo jade á tà á 70
Á ta gbogbo dúkìa, a sí sè ìsirò owó
Lójú esè ni yóò kówó re ilé babaláwo
Babaláwo a gbowó, á ní
Má a lo, Olórun yóò bá yanjú ìsòro náà
Télè ilé oko re ló wà 75
Aso wíwò re bùkátà rè ni
Ìró ríró bùkátà rè ni
Ojú lílé re bùkátà rè ni
Yerí etí lílò re, bùkátà re ni
Ègbà orun lílò re ni 80
Òrùka lílò re, bùkátà rè ni
Agogo lílò re, bùkátà rè ni
Bí o fé je Tuwo dawa
Bì o fé je Iyán
Bí o fé je Tuwo Shin kafa 85
Ohunkohun tí o bá fé je
Oko re gbódò sètò owó rè
Ó gbódò se ìtójú bàbá àti ìyá re.
Nísinsínyí tí o kò ní oko mo
Gbogbo ohun tí o bá fé se 90
Ó di dandan kí o gbé bùkátà
Kì í se èbi oko re
Gbogbo ènìyàn ti gba iyen
Je kí n fun o ní ìmòràn ìwo oko
Ìyàwó re ni èyí 95
O gbódò gbé omi ìwé re lo sí balùwè
O n se ìtójú àwon ìkókó
O gbódò gbé oúnje fúnràa re
Tí o bá ní àlejò, ìtójú won fúnráà re
Bí o bá ní erú láti se gbogbo èyí 100
Èló ni o fé san fún un
Bí òfin
Awon ìyàwó gbódò mu ìgbéyàwó bí ohun elegé
Awon oko gbódò mú ìgbeyàwó bí ohun elegé
Ara àwon oko ni èmí pàápàá wà
[edit] JAWABIN AURE
Jawabin aure za mu yi,
Da farkon Allah ne gaba,
Manzan Allah na biye
To uwa da uba suna biye
Sannan aure na biye 5
Mai-gida da uwar-gida
To ku duka zan maku gargadi,
Shin hakkin komai daga duniya,
Hakikan kome in kun tuna
Wallahi Allah ka maku lamani, 10
To kun ga ban de bakkin aure.
Mai-gida da uwar-gida,
In an yi fada dan annabi
Don Allah a bar saurin fita,
To amma in an bibiya, 15
Wata kila gidan da munafikai,
Abin da mai-gida ya yi,
A je a fada wa uwar-gida,
Sannan ita ba ta bincike,
Abin da uwar gida ta yi, 20
A zo a fada maka mai gida,
Sannan kai ba ka bincike,
Kun san ba a kwana bakwai,
Sai kun ga husuma ta hadu
To daga nan kuma sai rabuwa ta zo. 25 Shin bayan in rabuwa ta zo
To kiran amalanke fa naki ne,
Ki kwashe kayan kin jiya,
Ki kai can a gida naku,
A sam maki daki dan kadan, 30
Kin sa kayan sun lankwashe,
Sannah wasu ma sun makade
Kana wasu ko sun tasgade,
Sannan wasu ma sun farfashe,
Maigida ba laifinshi ba, 35
Kin ga ke ma ba laifinki ba,
‘Yan gulma da makircin tsiya,
masu son raba sunnar Rabbana,
duk mu taru mu tsittsine masu,
to, mu ce masu Allah ya isa 40 da can kina ko gidan miji,
ki gyara gadonki ki je ki hau,
to yanzu da ba ki da maigida,
sai dare ya yii a cane maki,
ga tabarma je ki je, 45
maza je ki cikin yara ku kwan
daga nan bacin rai sai ya zo,
sai ka gan ta gidan boka kuma,
“Boka kai mini magani
Boka ga zama kasarsa a hankali, 50
“Ai ki biya ce tai miki magani
A ruwan randa kuma anka sa,
Idan ke kin sha ruwan,
Idan shi ya sha ruwanl
Ai tilas ne sai kun rabu, 55
Yarinya ai ga shi
Ko kun rabun
Sai ka ji dai matar gida,
Ta cane “To mallam yaya za a yi
Sai ka ji boka ya ce cene, 60
“Akwai ko yadda za ce cene,
Ki ba ni farin rago biyar,
Turmin alawwayo guda biyrar,
Ki ba ni kudinki sule dari,
Ki ga yanzu zan maki magani 65
Sai ka ji mata ta cene,
“Wannan abin mai sauki kuwa.”
Ta koma can gida,
Jawo kwalla sayar,
Jawo bokiti ma sayar, 70
Ta sayar ta kulla kudin
Ta kai wa boka nan da nan,
Boka ya hamdame:
“To je ki Allah zai mana magani”
Da can kina ko gidan miji, 75
Rigar sawa sai ya yi,
Zanen daurawa shi ya yi,
Su dan kwali shi za ya yi,
Su dankunne duk sai ya yi,
Sarkar wuya duk shi za ya yi, 80
Su zobe duk shi za ya yi,
Agogon bannu sai ya yi,
Tuwon dawa in za ki ci
Sannan sak wara in za ki ci,
Tuwon shinkafa kin jiya, 85
Matukar in dai shi za ki ci,
Mai gida yai tandi,
Uwa da Uban ya kula dasu,
To yanzu da ba ki da maigida,
Wannan abu duk ke za ki yi, 90
Haka kin ga asara taki ce,
Mai-gida don ba laifinsa ba
Dubban jama ‘a sun tabbata,
Maigida kai zan maka gargadi,
Kai ma wannan matarka ce, 95
Ruwan wanka ita za ta kai,
Ta lura yara kankana,
Sharar daki ita za ta yi,
Ta tuka abinci ka zo ka ci,
Shin Mallam ko bayinka ne, 100
A wata nawa za ka biya su ne.
To don hakanan dada kun jiya,
Mata ku rike aure da kyau,
To maza ku rike aure da kyau,
A cikin ka maza ma har da ni 105
[edit] A Wedding Song
It is a comment about marriage I want to make
First god is the leader of all
Followed by the messanger of God
Then the mother and father are following
Then marriage is the next 05 Please both husband and wife
I want to pass a word of advice to both of you
The right of everything in this world
Surely the right of everything, if you remember
Definitely, God can overlook a lot of things 10
Except the right of marriage
Please husband and the wife
If there any quarrel For God’s sake
Don’t get annoyed quickly
But probably if you investigate well 15
There could be some hypocrites in the house
Whatever the husand does
Is relayed to the wife
The wife will not investigate
What the wife does 20
Is relayed immediately to you the husband
And you will not investigage
You know, its difficult to spend seven days
Without one trouble or the other
From there, divorce could occur 25
Okay, if divorce eventually occurs,
You are to hire the barrow pushers,
Packing of the properties is your responsibility
Conveying them to your family house
They give you a little space to keep them 30
Some of the properties will get spoilt
Others will get damanged
Yet others are destroyed
Some will get broken
All these are not the fault of the husband 35
Neither is it that of the wife
But the hypocrites around
Why separate what God has joined
We should all gather to curse them
We tell them God shall judge 40
Before, you were in your husband’s house
You lay your bed and lie on it
But now that you have no husand
When night falls, they will tell you
Take the mat 45
Go and sleep with the children
From there, your mind will get spoilt
She will begin to visit herbalist
Please help me with the medicine
The herbalist will manipulates his tools and say 50
All these are the work of envy
She put the medicine in your drinking water
If you drink your water and
If he the (husand) drink water
It become necessary to divorce 55 And here it is, young lady,
You have divorced
Then you will hear the woman saying
Okay malam, how do we resolve it?
Then the herbalist will say, 60
There is a way out
You will give me five white rams, and
Five bundles of clothing materials
Then you give me one hundred shillings
You will see right now I will solve your problem 65
Then the woman will say
This indeed is a simple demand
She goes back home
Bring out this bowl and sell
Dispose out this bucket 70
She sold everything and calculated the total
And take it to the herbalist instantly
Herbalist collects them, and say
Go, God will remedy the situation for us.
Before, you were in your husand’s house 75
Putting on cloth, he must do it for you
Putting on wrapper he must do it for you
Putting on eye lips he must do it for you
Putting on earring he must do it for you
Putting necklace he must do it for you 80
Putting on Rings he must do it for you
Putting on wristwatch he must do it for you
If you want to eat tuwon dawa
If you want to eat pounded yam
If you want to eat tuwon shin kafa 85
Anything you want to eat
Your husband must save money for it
Your father and mother, he must take care of them
Now that you don’t have an husband
Everything you want to do 90
You now have nto bear all responsibilities
It is not your husand’s fault
Everybody has accepted that
Let me advise you the husband
This one is your wife 95
You must carry your own water to the bathe-room
You are now taking care of infants
You havew to sweep the room yourself
If you have visitors, you entertain them yourself
If you have slave to do all these 100
How much will you pay them
As a rule
Wives should hold marriage carefully
Husbands should hold marriage carefully
I am also included among the husbands 105
[edit] Orin Ìgbeyàwó
Ìgbeyàwó ni mo fé sòrò lé lórí
Lákòókó, Olórun ni asíwájú gbogbo èdá
Ojise Olórun ni àtèlé
Bàbá àti ìyá ló tún tè lé e
Léyìn èyí ìgbéyàwó ló kàn 05
Tokotìyàwó e jòwó
Mo fé fun yin ní ìmòràn kan
Ètó sí gbogbo n nkan láyé yìí
Dájúdájú ètó si ohun gbogbo ní ayé yìí tí e bá rántí
Dájúdájú Ọlórun lè fi ojú fo òpò nnkan 10
Àyàfi ètò ìgbèyáwó
Tokotìyàwó, e jòwó
Tí ìjà bá wà
Nítorí Olórun e máse yára bínú
Bóyá tí e bá wadìí dáradára 15
Àwon agbótekusoféye wà ní agboolé
Ohunkóhun tí oko bá se
Á di títò fún ìyàwó
Ìyàwó kò ní se ìwádìí
Ohunkóhun tí ìyáwó bá se 20
Ádi títò fún ìwo oko lójú esè
O kò sì ni se ìwádìí
O mò pé, ó sòro láti lo ojó méje
Láìsí wàhálà kan tàbí òmíràn
Láti ibè ìgbéyàwó lè túká 25
Tí ìgbéyàwó bá di títúká
O di kí o gba olómolanke
Erù kíkó di isé re
Kíkó won lo sí ilé òbí re
Wón á fùn o ní ààyè kékeré láti kó won sí 30
Lára àwon dúkìá wònyí á bájè
Àwon kan á polúkúmusu
Àwon kan a di rádaràda
Àwon kan yóò fó
Gbogbo eyi kú se nitori aisedeede oko 35
Bee, kì í se èbi ìyàwó
Bi ko se ti alábòsí agbo ilé
Tó fé tú ohun tí Olorun tí so pò
Gbogbo wa gbódò parapò fi wón bú
Ká so fun won pé Olórun yóò dá a fún won 40
Télè iwò ìyàwó, ilé oko lo wà
O té ibùsùn re o sì sùn lórí rè
Sùgbón nísinsìnyí tí o kò ní oko mó
Bí alé bá lé won a gbé ení fún o
Gbé ení 45
Kí ìwo àti àwon omodé jo sùn
Láti ibe èrò buruku a wonú okàn re
Yóò bèrè sí to ojúlé àwon Babaláwo
Babaláwo, e jòwó e se ìrànwó oògùn fún mi
Babaláwo á gbópèlè sánlè, á ní 50
Gbogbo wàhálà wònyí owú jíje ló fàá
Inù ìkòkò àmù re fi oògùn òhún sí
Tí ìwo ìyáwó bá ti bu omi mu
Tí okó náà bù mu
Ó di dandan kí ìgbéyàwó yín túká 55
Òhun sì rè é, òdómobìnrin
Ìgbèyàwó re ti túká
E ó gbó tí obìnrin òhún á ní
Babaláwo, a ó ti se é sí
Babaláwo a ni, 60
Ònà àbáyo wa
Lo wa, àgbo funfun máarùn-ún,
Ìgàn aso funfun márù-ún
Àti pónùn méwàá
Lójú esè yanjú ìsoro re 65
Arábìnrin á ní
Gbogbo ìyen kò sòro
Yóò padà sílè
A gbé igba jáde, á tà á
A gbé àwo jade á tà á 70
Á ta gbogbo dúkìa, a sí sè ìsirò owó
Lójú esè ni yóò kówó re ilé babaláwo
Babaláwo a gbowó, á ní
Má a lo, Olórun yóò bá yanjú ìsòro náà
Télè ilé oko re ló wà 75
Aso wíwò re bùkátà rè ni
Ìró ríró bùkátà rè ni
Ojú lílé re bùkátà rè ni
Yerí etí lílò re, bùkátà re ni
Ègbà orun lílò re ni 80
Òrùka lílò re, bùkátà rè ni
Agogo lílò re, bùkátà rè ni
Bí o fé je Tuwo dawa
Bì o fé je Iyán
Bí o fé je Tuwo Shin kafa 85
Ohunkohun tí o bá fé je
Oko re gbódò sètò owó rè
Ó gbódò se ìtójú bàbá àti ìyá re.
Nísinsínyí tí o kò ní oko mo
Gbogbo ohun tí o bá fé se 90
Ó di dandan kí o gbé bùkátà
Kì í se èbi oko re
Gbogbo ènìyàn ti gba iyen
Je kí n fun o ní ìmòràn ìwo oko
Ìyàwó re ni èyí 95
O gbódò gbé omi ìwé re lo sí balùwè
O n se ìtójú àwon ìkókó
O gbódò gbé oúnje fúnràa re
Tí o bá ní àlejò, ìtójú won fúnráà re
Bí o bá ní erú láti se gbogbo èyí 100
Èló ni o fé san fún un
Bí òfin
Awon ìyàwó gbódò mu ìgbéyàwó bí ohun elegé
Awon oko gbódò mú ìgbeyàwó bí ohun elegé
Ara àwon oko ni èmí pàápàá wà