Professor Oyewole
From Wikipedia
PROF. OYÈWOLÉ
Lílé: E má pa Professor mi fún mi
Ọmolúwàbí eeyàn ni
Oyèwolé Professssor mi
Olábíwonú mi o Kòfésò mi dada 480
O re India oo gbayi bò
Iwa rere ló e gbe dáyè tó wà dandan
Bàbá Fúnmiláyò mi ooo ye
Osó kan ò rí tie gbé se
Ìwà rere ló nilé ayé o e se rere 485
E se rere kó ba lè ye gbogbo wa, iree
Ègbè: E se reree, ye o, e se reree
E se reree, kó ba lè yee wá o
Lílé: Ire, ire, ire, ire, ire ire
Ègbè: E se reree, e se reree ko ba le ye gbogbo wa 490
Lílé: Ire lo pe
Ègbè: E se reree, yé ò e se reree
E se reree kó ba le yee wá o
Lílé: Ire, ire, ire, ire ló nilé ayé ò
Ègbè: Ee se reree, e se reree 495
Kó ba lè yee wa o
Lílé: Òò màmá
Ègbè: E se reree, yé ò e se reree
E se reree kó ba lè yee wá o
Lílé: Ireeeeee 500
Ègbè: Yé ò e se reree, e se reree
Kó ba lè yee wá o
E se reree, yé ò e se reree
E se reree kó ba lè le yee wa o
Lílé: Asoremásìkàà ìyẹn mà lésan tiè 505
E se rere kó ba lè ye gbogbo wa ire
Ègbè: E se rere, e se rere o
E se rere kó ba lè ye wá o
Lílé: Ìwà rere ló nilé ayé o e se rere
E se rere kó ba lè ye wá o 510
(Iree ye o)
Ègbè: E se rere yé ò e se rere
E se rere kó ba lè ye wá o
E se rere yé ò e se rere
E se rere kó ba lè ye wá o 515
Lílé: Yee mamà
Ègbè: E se rere yé ò e se rere
E se rere kó ba lè yee wá o
Lílé: E se rere ye o e se rere
E se reree kó ba lè yee wá o 520
Ègbè: E se rere yé ò e se rere
E se rere kó ba lè yee wá o
Lílé: Bòdá Lálekan, bòdá Ládipúpò, e se rere
Aya Fáturórì mi e se rere o dara
Ègbè: E se rere ye o e se rere 525
E se rere kó ba lè ye wá o
Lílé: ìwàà rere ló ye ká ma hù
E se rere kó dára
Folásadé o e se rere
(Iwa rere ló ye ò) 530
Ègbè: E se reree ye o e se reree
E se reree kó ba lè yee wá o
Lílé: Baba Taju kó dára o bá mi see rere
E se rere kò ba lè yee o
Ègbè: E se rere yé ò e se rere 535 E se reree kó ba lè yee wá o
Lílé: E see rere yé ò e se rere
E se rere kó ba lè yee wá o
Ègbè: E se reree yé ò e se reree
E se reree kó ba lè yee wá o 540
Lílé: Onákoomáyà mi oo e se rere
Baba Bísólá, è se rere
Dákun o e se rere
Awo Amódemájà
Ègbè: E se rere ye o e se rere 545
E se rere kó ba lè ye wá o
Lílé: Onákoomáyà Baba Bísólá mi dábò
E se reree awo amódemájá iré bá mí
Ìwààà rere ló gbee dáyè tóo wà o
Ègbè: E se reree ye o e se rere 550 E se reree kó ba lè yee wá o
Lílé: Iwaa moode maa ja mo o
Oko Mopélólá toju ònákómáyà baba wa ni
Ègbè: E se rere yé ò e se rere
E se rere kó ba lè ye wá o 555
Lílé: Ire ló pé o e se rere
Amódemájá ònákómáyà baba wa òré ni wón
(Ọba tó dá yín dákun má yà yín babaa a)
Ègbè: E se rere yé ò e se rere
E se rere kó ba lè ye wá o 560
E se rere ye o e se rere E se rere kó ba lè yee wá o
Lílé: ìwà rere ló nilé ayé mi oo e se rere
E se rere kó ba lè ye gbogbo wa
Awo Clement (ìdílé tó lókìkí mi o) 565
Ègbè: E se rere ye o e se rere
E se rere kó ba lè ye wá ooo