Shakara
From Wikipedia
SHAKARÁ
Lílé: Èébà 270
Sisí onísàkàrá
Bèbibèbi onísakàrá ó yeyè
Torí póbìnrin ò rówó sampú
Tí ò lówó sampú
Póbìnrin ó soge, tí ò rówó soge 275
Pé yóò ra lipstick o,
Tí o lówó lipstic
Ló ba bere shakara
Ló ba bere pupking
ó bere shakará 280
Ìyàwó oní shakara èèè, èébà
Ó féé serun orí o
Ó féé serun ojú
Ó féé se tabéè láàrin ijó kan
Bó jé ten naira lo mí gba lósù o yeyè 285
Ìyàwó féé serun ‘five hundred’
Ó féé se ‘panicure’
Ó féé se ‘penicure’
Ó féé sèékánná owó
Ó féé sèékánná esè ò 290
Irú yàwò wo lèyí oo Nàìjíríà!
Bébí ònà dà kóko mámà jalè sé
Auntí a bóófé lémi ní Nàìjíríà ni
Ìyàwó fee gba mi sówó osí o
Sháa sháá sháá shaakàrá ó yéye 295
Ègbè: O o shakaráá
Ó ó shakaráá
Lílé: Bèbí bèbí shàkàrá ó yeyé
Ó ó shakaráá
Ègbè: Aunti onípànkékè ó yeyè 300
Ó ó shakaráá
Lílé: Ìyàwó onísàmpú oo yeyè
Ó ó shakaráá
Lílé: Shashashasha yeyeye
Ègbè: Ó ó shakaráá 305
Lílé: Àùntí oníshakará o yeyè
Ègbè: Ó ó shakaráá
Lílé: Bebí bèbí bèbí
Ègbè: Óó shakaráá
Lílé: Bèbí yeeeee 310
Ègbè: Ó ó shakaráá
Lílé: Bébí onípànkékè o yeyè
Ègbè: Ó ó shakaráá
Lílé: Ìyàwó onishakará o yeyé
Ègbè: Ó ó shakaráá 315
Lílé: Bèbí bèbí bèbí oníshakará ó yeyeye
Ègbè: Óó shakaráa
Lílé: Yeye yeye shakara
Yeyeye shakará
Ègbè: Óó shakaráa 320
Lílé: Ìyàwó onípànkékè o
Ègbè: Óó shakaráa
Óó shakaráa