Yakubu Gowon
From Wikipedia
Yakubu Gowon je omo orile ede Naijiria lati apa gusu. Gowon je Ogagun ni Ise Ologun ile Naijiria be ni o si je olori orile ede Naijiria lati odun 1966 de 1971. Ni igba ijoba Gowon ni Naijiria ja ogun abele lati odun 1966 de 1971 nigbati apa ila oorun ti a mo si Biafra labe Ogagun Odumegwu Ojukwu fe gba ominira lowo ile Naijiria.