From Wikipedia
Awon eyi pataki ninu ona eto toorun (ki se bi won se tobi si, lati apaosi de apaotun): Pluto, Neptunu, Uranosi, Satonu, Jupita, agbegbe awon irawo,
Oorun, Mekiuri, Fenos,
Ilẹ̀-ayé & Osupa, and Maasi. Atun ri Okutaina orun kan ni apa osi
Ọ̀nà ètò tòòrùn (solar system) ni oorun ati awon ohun oke-orun ti o n yi ka.