Naijiriya
From Wikipedia
Naijiriya, Nigeria ni ede geesi, je ikan ninu awon orile ede ni ile Afirika. Naijiriya ni orile ede kan soso ti awon eniyan po si ju ni ile Afrika. Naijiriya pada si ijoba alagbada ni odun 1999 leyin odun meedogun labe ijoba ti awon soja. Awon ile Ibini, Sadi, Nije ati Kamerunu ni awon ile ti o sunmo ju si Naijiriya.
Awon ilu ti so se pataki ju ni Naijiriya ni Abuja, Eko, Ibadan, Ilesha, Kalaba , Warri, Pot Akotu, Enugu, Kano, Kaduna, Onisa, Nnewi, Jos, Ilorin, Maiduguri, Aba, Bausi, Oweri, Sokoto, Ile-Ife ati Ilu Ibini.