Nọ́mbà àdábáyé
From Wikipedia
Ninu Imo Isiro, awon nomba Adabaye, tabi nomba Adaba (Natural number) le je okan ninu akojopo {1, 2, 3,....} (eyun nomba odidi alapaotun) tabi okan ninu akojopo {0, 1, 2 3,...} (eyun gbogbo nomba ti ki se ti alapaosi).
A n lo nomba adaba fun kika ("Ọsàn mefa lowa ninu apẹ̀rè yị); be ni a si tun n lo won fun sise eto elesese ("Ipo keji ni Bùkọ́lá mu ninu ìdíje sàyẹ̀nsì odun yi").